Skip to content Skip to left sidebar Skip to right sidebar Skip to footer

Modakeke Anthem

Reading Time: < 1 minute

ANTHEM

Chorus: Modakeke Akoraye
Ilu ibile e wa,
T’ife t’isokan la fi n bara wa lo,
A mo ‘se aje, akikanju la je,
B’ota n hale won nse lasan ni,
Ori eye ko ni s’aigbe feye

1. Oyo nile ibe lati se wa o
T’a fi wa tedo pelu isokan
Eye Ako lo fun wa loruko
Akoraye t’a nje a o daje
Ogunsowapo a o tuka mo o
Adupe Olu to so wa dodidi
(Chorus)

2. Modakeke bi mo bi akinkanju
Akonimora olufe ilee baba eni
Eni to ni tara sise aje ni wa
Ise agbe atowo layan laayo
Ka ke p’Eledaa nigba isoro gbogbo
Ka pa ‘na ote pelu isokan
(Chorus)

3. Ka pana ote, ka ma yan ra waje
Fun tesiwaju ilu wa
Ka se pade po pelu akin egbee wa
Kaakiri orile-de
Eyi la fi le ni ‘losiwaju gidi
T’a fi to gbangba sun loye

3 Comments

Leave a comment

Your email address will not be published.